Anda di halaman 1dari 30

QRfiNMLA!

^OTT ^ C0 *AN*\

First

Printed

1908.

Second

Print

1972.

Printed by:OM O LA Y O

ST A N D A R D PRESS O F
A kure R oad, P. O. Box 3,
A D O -E K IT I.

N IG ER IA

Alufa, Lijadu iiiiiu Igbo-lfa.

IFIJUBfi,

A l u p a T o m H a r d i n g Oyinbo onis^ Olorun ti o se


Qga-lwe fun awpn Akpko Ise Olprun ni Ile-I^kp Giga ti ('.M.S.
li fik'6 lati pdun 1884 de 1887, Alabojuto Isp Olprun IAbpokuta lati pdun 1888 de 1895,Iriju ati Akpwe fun C.M.S. lati
pdun 1896 de 1902, Alabojuto Isp Olprun 1 Ibadan lati pdiin
1892 titi di pni
ati nipa anu Olprun, Iwp ti o kii li iilipba
larin awpn Oyinbo onisp Olpran ni gbogbo Iwp-orun Afi'ika,
Iwp ni mo fi Iw e kekere mi yi juba loni.

Nigbati ise da awa mejeeji p6 ninu Ile-Eko Giga ti C.M.S. li


Eko lati pdun 1885 de 1890, Iwo bi oga-ise naa ati emi bi
alagbase, Qlorun gbin igi-ore kan saarin wa; O fi i fun awa
mejeeji lati maa roko-si, On paapaa si nrojo ibukiin re le e
lori. Mo dupe lowo Olpruri pe igi-ore naa ti On gbin saarin wa
ti hu, o gbile, o si bcresi iso eso nisisiyi.
MO FI IWE YI JUBA RE ni iranti aniyan re igbanaa pe
a ba le ri owp awon I we Kika li ede Yoruba lati maa se bi
iranwo fun awon Akeko Ise Qlorun ni lie Yoruba si ati-mo
iwa ati ise awon enia ile wa daju, fun ilo won bi Oniwasu
iebin pla. Ati nigbati o di mimo fun o pe mo ngbidanwo
ati-se akojo iru awon iwe bawpnyi, ppp iranwo li o ti se fun mi
nipa prp iyanjii ati inawo re fun mi si pna naa. Ipase tire
kannaa ni awpn Oyinbo miran bi awpn Oloogbe Alufaa
J.W. Dickenson ati J. Brayne ati Yeba Marion Goodall tele
nipa inurere wpn si pna yi, awpn eniti o ti goke odo Jordani
si ibi isimi wpn. Ki Olprun masai fi wpn si ipo rere Ipwp
ptiin Re Iphun.
Ninu awpn ore tootp ti mbe laaye sibe ti ko si ye ki ng
gbagbe nihin ni Olpla obirin ti Arkidiakoni Melville Jones fun
iyanju re igbagbogbo ti 6 dabi tire si mi ati si ohun rere gbogbo
ti o je ti pmp ibile Yoruba.
MO TUN JUBA NYIN O, nitori enyin ko korira
Sekooni ninu enikeni laarin He enia dudu; kaka bee enyin nfi
tpkantpkan nyin kp-ni pe Aba-enu-lasan ko le so ohun rere ti
a nfe di t eni.
*
MO TUN JUBA NYIN O, nitori enyin ko wipe ki eniti
6 ri-je- mase je, enyin ko wipe ki alairi-je f ebi sun, enyin ko
wipe ki eniti otutu npa mase yana, enyin ko wipe ki eniti
ooru nmu mase sun oyi, beeni e ko si wipe ki oligi eeji mase
npse sina! Ki Qlprun biikun ise nyin laarin wa, ki O si fi ppplppp
eso itunu ke nyin latinu re wa. Amin.
Iwe mi kekere yi je kikini ninu eso naa; ugbpn adura pkan
mi ni pe ki 6 le je agbara nla Ipwp awpn iranse Jesu Kristi ni
ile Yoruba, ati ki 6 si le ft bee di iwe - ayple kan fun gbogbo enia
Emi ni Ore re nitooto

E. M. LIJAEiU
Gbangan Ajihinrere-lpfe
Ode Ondo, July 7, 1907.

SI AWON OLUFE IFE ILE IBI WON


Enyin Olufe,
Bi ojo se ng gori ojo, ti ose ng yi lu ose, ti igba si ng tele
ra won: be e Ipclun ori iwe yi ng di pupo'to be e ti a ko ba ri
eni-bi-eni enia-bi-enia fowosowopo se atunse ati atunte iwe na
ki n w p n siran asodefunifihanatikikagbogboenia yio di igbagbe larin wa, iranti ki yio si si fun un mo Toril? ede wa yi i.
Pe Olorun gbe awon olufe ile ibi won dide ni sa a yi, ti
nwon si nfi tgkan tara ng fe ki asa ati itan ile ibi won wa ni
pipe sansan je ohun ayp ati iwuri fun mi. Awpn sa a li o rp
mi lati ypda atunte awpn iwe mefa ti baba mi agba Ologbe
Alufa E. M. Lijadu e: a .n .:- (1) Aribiloso (2) Ifa (3) Ode
Gaga Ara Ilujugbe (4). Gram ma Yoruba (5). Orunmla ati
(6). Sobo-Aro-bi Odu Apa I & II ati awpn iwe miran ti koi
ti fi oju kan erp itewe.
Nigbati ohun wa si ti pkan lori eto yi, a da egbe kan sile
ti a pe ni Egbe Oludabobo Asa Yoruba. Ie egbe yi ni lati
ma a ran enikeni ti o ba ni ife asa ile Yoruba Ipwp. Egbe
na a yio ma se iranlpwp fun tite iwe ti o ba niye lori ti yio si se
ile wa yi ni rere, bakanna a ni yio ma sa gbogbo agbara re
Ipnakpna lati ri pe awpn ohun abpba ile wa ti o spwpn ko
po o ra mp wa loju bikosepe a lo wpn fun ire, ogo ati igbekele
orile-ede wa. Nitori idi eyi.....................
Mo juba Olprun Eleda, Eniti o fi apakan pgbpn re ta w^
Ipre. M o si dupe gidigidi Ipwp awpn enia wpnyi - ti wpn
ba mi pile egbe yi ti wpn si se akojp owo fun atunse ati atunte
awpn iwe na a. e . n . O l o y e S. A. Fawehinmi, (2).
lyaafin Fpla Fasida. (3). Qgbeni Dptun Odunuga. Ibere li
eyi, a ni igbagbp wipe e o tewp gba awpn iwe na bi wpn ba se
njade li pkppkan gege bi awpn baba wa se gba wpn tayptayp
nisa-aju. Mo si ni ireti pe lehin eyi, e o gbiyanju lati darapp
mp wa ninu Egbe Oludabobo Aa Yoruba. Mo ki yin o
eniyin ara: Mo juba yin o enyin agba, ki Qlprun ma fi eyi
se asemp fun wa o. Aje.
Ajihinrerelpfe House,
64, Lokun Street,
P. O. Box 76,
Telephone 85,
Ode-Ondo.

Emi ni Tiyin Nitotp,


Enipwp E. A. LIJADU,
Oniporisan Keta
Alufa Ajihinrerelpfe,
Ondo.
10 : 12 : 71.

iv^^E n.
ORUNM LA
Bi a o soro Oriinmla li asojale, a ko le saispro ohim meta
wonyi si i Eki'ni, ohun Iwa-Olorun tf awon babaiila wa
pin fan u: ekeji, ohun Iwa-enia ti nwon fifun u peiu: eketa,
awon ekoyeko ti o ti enu re jade.
Ekini ni nikan li a o dawole iiisisiyi ninu iwe yi; a o fi meji
iyoku sile digbose.
Nwonyi li oold Orunmla ti a fi se ipile asaro wa ninu iwe
yi
OR.UUNMLA, Heeri-ipin; Ibikeji Olodumare;
A-je-ju-oogiin, Obiritii,-A-pijo-iku-da.
Oiuwa mi amoimotan, a ko m o o tan ko se,
A bii mi) 6 tan iba se ke.
Oiuwa mi Olowa aiyere; Omo Elesin lie-Oyin,
v/
Omp prope kan t o saran dpgi-dpgi.
Oiuwa mi opoki a-mu-ide-soju,
Eekan ko je kekiin hpra, asaka-saaka akiin;
Omp Osp-ginm Tapa ti nwev/u ninii;
Omp Oso pade mpwo p ade mese o mbeere atepaa oje.
Oiuwa mi Igbo, pmo iyan birikiti inu odd;
Omp igbii ti nsdpe jiajia.
Ikii diidu atewp, Orp ajepo ma pon;
Agiri Ile-Ilpgbpa, a-boioo\vu diwere ma ran.
Oiuwa mi A-to-iba -jaiye, Orp a-biku-jigbo;
Oiuwa mi Ajild, Qgege a-gbaiye -gun:
Odiidii ti idu ori emere; 6 tun ori ti ko suan se.
Omp eiejo ti nrin mirjn-mirln lori ewe,
pm.p arin ti irin Ode-Owp saka-saka.
N IN U ooki wonyi a ri isi kan ti o tpka si ohun Iwa
Olprun, a si ri isi miran ti o toka si ohun Iwa-enia: a o ko
mu awon ooki ti o bo sabe isi ekini loroori.

ORI

ORI

O RUNM LA .

Itumo oruko yi bi a ti gbg p lenu awpn babalawo ni pe


Orun li o mp oola ija / tabi Orun li n mo ilaja. Nipa
o fu k p ^i awoiHcePeri lie wa jewp pe ija k a n ^ t a k i mbe laarin
aiye ati prun, ati pe awpn ko mp eniti yio laja naa, beeni awpn
ko mp pna ilaja naa. Ninu awpn ese-ifa ti o tele nihinyi a o
ka ti ija yi.
1. Orunmla nl 6 di paaram iila; mo ni 6 di paaram iila;
6 ni * pde aiye ton tpde prun ma pade loni na o ! IrosuEgutan.
* Nijo kan, Odg prun ran aya re wa spja aiye, awpn araiye ko mp p,
nwpn ba a ja nwpn lu u; sugbpn Odp aiye ri bi a ti njp p ni iya, o saanu rp
laimb p ri, o gba a silp Ipwp won. Nigbati obirin naa pada de ode prun, o
robin fun pkp re iru iya ti araiye fi je on, ati bi Ode aiye ti saanu fun on.
Njp pdp prun ranp dupe Ipwp pdp aiye, o si bp e ki o masai wa pade on ni
ipinna aiye on prun titi pjp mpta. Ojp p6, awpn pdp mejeeji gbe agbe emu
kppkan wa sibi ade; nigbati nwpn ri ra-wpn, nwpn yp, pnikini si fi agbe
pmu ti o gbe wa tprp fun pnikeji re bi ohun ade. Bi nwpn ti jump nmu pmu
yi nwpn nsp asiri iwa aiye on prun fun ara-wpn, nwpn si nta gpdpgpdp inu
ago wpn sori ilp nibikannaa. Nikehin nwpn pinnu ati-ba ara wpn da
majpmu, ki oju ilp it-pse-si yi le di ibi oritp fun ati enia ati pranko. Lati
se e daju, nwpn gbe pfin jijin kan sibp gangan, nwpn si fi irawe bo o loju
pe pnikpni tabi ohunkohun ti o ba dasple oju ibp ki o maa lu pfin.

ORI I

2. Ekiti pete, adafa fun Ode aiye a bu fun Qde grun;


ani ki nwgn rii eiyele merin on egberin, ki igbo ti nwgn nig
de le j;an vygh. Ode grun iiikan To ru, *Ode aiye ko rii.Irosu-Eg&an.
p^lupplu nwpn se ibura pe ?ni ti o ba t^te de ibe ki o maa la ohunkohun
ti a ba ri ninu gfin naa Ipgbopgba lati mu idaji ki o si ku idaji silp fun
enikeji. Etu jin fin yi a ia a, ekiri jin i a la a; nkan ko te nkan ko wp.
Aja pdp prim lu pfin yi; nigbati pde aiye ba a nibp o la a meji gpge bi
adehun, o fi idaji silp fun pdp prun. Inu bi pdp prun lati ri iwa pdaju yi,
nitorina li o $e Ip ifi pdp eku kan bp esu lpw6 ki o le ba on gbpsan lara
pdp aiye. Esu gba, esu gbp. Bi iya pdp aiye ti nja ewe plu kiri ni agbegbe
ibp, esu bi i Ip jin spfin yi, o si yara Ip iwi fun pdp prun. Odp prun
ko benibeji o la arugbo naa: bi o ti ngbe idaji tir^ Ip ni pdp aiye de,
o ke; inu bi i o ni, biotiwu ki o ri, iwp le wipe o ko mp iya mi? Onitphun dahun o ni biotiwu ki o ri, iwp na le wipe o ko mp aja mi?
Awpn mejeeji bprpsi ija, o si pp tobe? gbogbo araiye pejp Iptun, gbogbo
ara prun pejp losi; ko si cniti o to isunmp ibi ija yi, tptuntosi nkigbe
si ara-wpn wipe p la wpn, p la wpn! Awpn miran si nwipe tani yio la
wpn, tani yio la wpn? Nigbayi ni Olodumare to ijade wa si aala ija naa.
O si beere idi r^ O gbp tan, o ni ki awpn mejeeji Ip mu ogoogoji wa, nwpn
se bpp. Olodumare wa tan awe meji oku arugbo naa le-pp o si sp p di
odidi; sugbpn o fi ogoji kan sami si ibiti a ti la a; o si fa iya pdp aiye fun
u pada; inu ara aiye ati ara prun dun tobpp ti gbogbo wpn da ohun pp
nkigbe wipe Orun mo won ila ! Orun mo won ila! Ayaani a mgbp
orukp ORUNMILA. Awpn p3p mejeeji si mu imp kansoso nwpn di i
mu nibi eji rp, nwpn fa a ya mp ra wpn Ipwp Ipgbppgba nwipe Paramila,
paramila, pdp aiye on pdp prun ko ni iri ra m6 lai. Ayaani a nya im6
kd ra pni li pbi laini atunse mp.
* Lati pjp ajayamp ni, Qdp aiye ati pdp prun ko tun nfoju kan ra wpn
mp kiki pe nwpn a maa kesi ara-wpn bi pkan ba spdp ja ipinna. Bi Odp
prun ti ndegbp tirp Ip nijpkan, o ba pyin nla marun kududkudu pade labp
pantiri o si ko o. O de ipinna o kesi pnikeji rp wipe Odp aiye pele o,
wa ko nkan ti mo fi sile de p nibi yi o; o wi tan o pada s ileba tire.
Odp aiye ti ko ri pran pa nijp yi wa wo ipinna, o ba pyin nla meji wpnyi,
o ko wpn Ip tayptayp; wara ti o si ti de ileba re, o se wpn jp. Ojump
Odp prun Ip ibe awpn pyin mpta tirp wo nibiti o ko wpn Ip ipamp si, pnu
ya a lati ba pgbawa owo-okun niwaju pyin kppkan: o si yara gbe owo naa
kuro, o tun ilp ibp se daradara. Ojump pjp kpta mp, o tun ba owo bee
nidi pyin kppkan. Nigbana ni o wa ilp si ipinna o si ke - si pnikeji re,
nwpn si njp ra wpn bayi: Odp aiye, p^lp o!
O-o-o-o-o-o-o.
O ti se pyin rp ijpta o?
Sise ni mo se e jp o
Bo Io ti ri Ipnu rp o?
O ma dun ladunju o !

Nigbana ni Odp prun dahun wipe Haa! o tan o ku o, iwp pdp aiye ko
ni ila m6 o. $iigbpn pdp aiye yara dahun wipe Eyi o wu ki a gbe inu
ile aiye sb, Orun li o ma ni Ila o ! Ayaani a nwipe Orun-nila. Qrunmla.

ORI I
3. Ajo awo Ile-aiye, Abemo awo ode Isalu-pnm, awon
mejeeji ni mpade kom gnipi'nna aiye on prun: a ni ki nwpn
rubp ki obirin kansoso t o wa laarin v/pn ma le ba eto je mp
wpn Ipwp. Awpn mejeeji eti gbonran sebp nwpn ko tu T a
nwpn ni kini obirin kansoso iba ti se le ba eto aiye on prim
je mp eni bi awpn Ipwp? Obara-meji.
4. A-r ppte-sa ko s ojo. Oyin si tan f afa dele, eenin
si tan f agan dele; a difa fun *araiye a bii f ara prun nigba
nwpn ngbogun ti ra w pn; a ni ki kaluku wpn ni akoto kan
oyin on akoto kan ekp fifP. Ara prun nikan Id rubp: araiye
gbp nwpn ko n i. Irete-Sa.

c/

*Obirin naa a maa j? Obi, aya Abemp awo ode isalu prun ni isc.
Abemo ti Ip idebp si pran ara obirin re y i , a ni ki o ru ewurp dudu kan on
egbaafa,ki o le bimp, eiyple niprin on pgberindilogun ki owo le ya wa ba
wpn. Abemp ru ti owo ko ru ti pmp . Ojp mpe Obi ko bimp, inu re
baje; o si sa wa ije Ajo awo ile-aiye. Ajo da awo, ebp ijpsi ti a yan fun
Abemp fun Ajo. Ajo gbp o rubp pmp, Obi si bi pkansoso fun u. Nigbati
pdun yipo, ti pjp ati -lp,si ikomp pe. Obi tple Ajo Ip ipade Abemp; inu bi
Abemp pipp lati ri pe Ajo te obirin on mpwp kadun li aitifi ran.sp^si on:
bepni Abemp here si pro buburu isp si Ajo. Ajo si mbinu pwe pe Abemp
ko tilp mu suurii gbohun kan Ipnu on ti on diyeinu mu Obi latinu ile-aiye
wa ipade re. Beeni ija di nla laarin wpn. Obi takete sokeere on nworan
wpn, ko si eniti yio laja o di ajaku. Nigbati o rp awpn mejeeji ti wpn
si nsimi Ipwp ni Abemp wa ikesi Ajo wipe Ija iwere ni a ma ngbe ipinna
aiye on prun ja yi o: ko si omuuja, ko si plaja; nitori ki aiye le baj? ki prun
le bajp ma ni Obi se ti pdp emi Abemp Ip spdp rp. Njp , Iwp Ajo awo
ile-aiye o ma wa ki a meti ko eti, ki a mu ohun sapo o! Bppni inu
awpn mejeeji si tutu, nwpn si Ip iwp ikomp: nibp ni nwpn si ti peropp
lati wa pa Obi tan ija aarin wpn. Nwpn se bpp nitootp, nwpn di oku
Obi sinu apo kan, nwpn si fl ha spgbp igi kan li eba pna, nwpn ba tiwpn Ip.
Nijp kpta ni Orisa nkpja Ipna ibp o ri oku Obi li egbp igi, o ji i dide o si bi
i leere bi o ti se de ibe. Nigbati Obi robin fun u tan, orisa dahun pe
o dara o, ng ko le ja wpn niyan; eyiti nwpn se naa ko bum o. Bppli
o si tun di Obi sinu apo naa, o si fi ha sibiti o gbe ba a li pgbp igi, o ba
tirp kpja Ip, Ayaani oo ri i, a mpa obi tan ija gbogbo ni ilp wa.
*Ni saa kan, awpn araiye sigun nip ba ara prun ja; sugbpn bi nwpn ti
de phin-odi prun nwpn ba ppplppp akoto pkp-flfp ti a po oyin igan mp,
n vpn ko mp pe ewp mbe nisalp gbogbo akoto wpnni, nwpn fi iwpra bprpsi
ekp naa imii. Lorii pjp naa ni gbogbo wpn ku patapata si phin-odi prun.
bjump mp ni jp keji, awpn ara prun jade si phin odi, nwpn ba kiki oku
araiye bpprpbe: nwpn wa ina oku meje ni pasan dide ni igun mprpprin ibudo
araiye.

ORI I
5. 6ke-yi-gbiri-wp d6 Io difa fun araiye o bii fun ara
orun nip jump wote, nijp ti nwpn yio jija egbonlori eran edii
kanso?o ti nwpn ri-pa; a ni ki araiye ma e melp-melp fun
ara prun 6: araiye ko nwpn ko gbo, ija de. Ejiogbe.
6. Hoo-hoo-mode To difa fun Asa, a bu fun Awodi, a
bii fun Igiin seketa gbogbo wpn; nijp ti n_^wpn nieri pe awpn
yio gbe * ebp pmp araiye Ip de prun. Asa Ip titi o re e o
ja wale.
nwQti ni ki awpn mejeje nwpnyi maa ru oku pgbp wpn kuro li ehin odi
awpn. Bayi ni awpn araiye die ti a ji-dide nwpnyi nwahala putii ni riru
oku awpn pgbp wpn pade ara yi ibudo wpn ka: awpn ara prun si wa nkprin
iya le wpn lori bayi pe; Oyin Ta mu
Ko ma le bara prun ja o,
Oyin Ia mu.
O gbogbo pip bplp ja o,
Oyin Ia mu
Ko ma le bara prun ja o
Oyin Ia mu.
Ayaani o p ri i bi araiye ti nru oku ara won kaakiri ninu aiye; oku li o
nru oku.
' ^
*Ekiri kansoso naa li araiye ati ara prun wote pa 1 o da ija silp laarin
wpn; nwpn ko fe ila a meji, ara prun ni awpn ni igbe c Iodidi, araiye ni
awpn ni igbe e Iodidi, ija de. Ara prun binu kp pran naa silp fun araiye
nwpn si pada Ip sprun Ip imu ojo. Kirikiri maiye, dugbpdugbp mprun,
ojo kakaka ko ta sile, pmp piye ko ri un sa-jp. Nigbati o ppn mo
araiye tan ni nwpn gbe pran ekiri naa silp, nwpn nwa pniti yio gbe e jp sode
prun fun wpn: olukuluku pniti nwpn flip nsa nwpn ko fp ilp. Nikphin ni
nwpn wa ilp gba aboyun kan mu, nwpn di pru pran naa rii u, nwpn ti i
jade spna prun. Aboyun gbe pru re de prun aanu se Olodumare o ni
Nitori ki iwp aboyun le ku spna prun kp li awpn araiye se ti p jadeyi?
Nje, iku ko ni ipa p, arun ko ni igbe p de; raura ki o wa pada ip inu aiye o .
Olodumare pasp a gb agbe omi kan le aboyun lori, a ni bi o ba ti de inu
aiye ki o fp p mple. Obi mu aboyun bi o ti wp inu aiye, irora si mu ki
o wa gbe omi mpri, o gbagbe ati-fd p mplp. O wpnu ile tirp tan ki o to
iranti fp p, o si bimp lojukannaa sinu agbara omi naa. Aygani oo ri i,
aboyun mbi sinu aabara omi-ra. Gbogbo aiye gbp pe aboyun de nwpn
riwp wa ki i w pe, O ku at prun bp! Ayaani oo gbp bi a ti nki
aboyun ti o bi titun. Aboyun bi tan a nwa omi ifiwp pmp bppni ojo giiri
kan o si rp ka gbogbo aiye.
*Nigbati ojo yi rp titi, o pa gbogbo ina aiye run susu, pmp araiye ko
tun ri ina se onjj mp; nigbanaa ni nwpn Ip wa pbp ti nwpn yio Ip fi gba ina
pada ti prun v/a. jb ? yi li a ru silp tan ti a ko ri pniti yio gbe e Ip, ti asa
awodi ati igun nieri ati-gbe e de ode prun fun wpn. Asa li o kp gbe e,
gbogbo pmp araiye si pejp nisalp nkprin bayi fun u bi o ti ngbpbp naa Ip
wipe:

ORl I
gbi'rihan, Awodi lo titi o re e, o ja w ale gbirihan, Igiin nikan
io ma gbebo ru de ode prun ninu won 6!Osa-Wori.
Akiyesi. Awpn ese-ifa nwpnyi ati itan won ti a ka
nihin fihan dajudaju pe pkan awpn baba-nla wa nje wpn
leri pe ija kan mbe laarin aiye ati prun; ati pe ija naa here
laarin enikan ti o duro fun gbogbo aiye ati enikan ti o duro fun
gbogbo prun; ati pe ija naa se lori oliun kansoso ti t ptun-tosi
wpn ni oju si ati pe araiye ko ro ati-tumba fun ara - prun
bikose lehin ppplppp igbe; ati pe lati prun ni onilaja ti wa
ati pe araiye ko ri ojurere ara-prun laisi ebp on etutu. Awpn
otitp nwpnyi ni iye lori jpjp ninu ipile isin awpn baba-nla
wa; nitorinaa a o mii awpn ohun akiyesi wpnni wa si egbe
prp Iwe mimp Olprun fun ifiwe ki a ba le ri itoye wpn.
(a) . Ija kan mbe laarin aiye ati prun.
(b) . Ija naa here larin enikan ti o duro fun gbogbo aiye ati
enikan ti o duro fun gbogbo prun.
Gene, iii, 17-19, 24 O si wi fun Adamu pe, Nitoriti iwp
gba ohun aya re gbp, ti iwp si je ninu eso igi naa, eyiti mo ti
pase fun p pe, iwp ko gbpdp je ninu re; a li ile bu nitori re;
ni ippnju ni iwp o maa je ninu re li pjp aiye re gbogbo; Egun
on osusuni yio maa hu jade fun p, iwp yio si m aaje eweko igbe:
Li oogiin oju re ni iwp o m aa jeun titi iwp o fi pada si ile;
nitori inu re li a ti mu p wa, erupe sa ni iwp, iv/p o si pada di
Hohomode, Homode: (2)
Asa mgbebp rprun, Homode:
O jo-jo ee mu jo, Homode:
O ra-ra ee mu ra, Homode:
O f ehin gbprun te o-mode, Homode.

(2)

Nigbati asa se e titi awodi gbe e, a nkprin naa fun awodi, bee gege
nigbati igun gbe e. Igun gbe ebp de prun tan, a de ina mpnu igba ademu
kan fun u wa, a si kilp fun u ki o mase fi igba naa kan ile titi yio fi de inu
aiye.
Igun de ori apata gbaramsa kan Ipna o ni on yio simi die, o si gbe igba
naa ka ori apata; sugbpn bi idi igba naa ti kan-le, beeni ina fo-yp latinu re o
si la igun lori borokoto. Ayaani oo ri i Igun se rere o pari.

ORI

erupe. Beli o le okunrin naa jade; o si fi awon kerubu ati ida


ina de iha ila-orun ti nju kaakiri, lati maa so ona igi iye naa.
Rom. V. , 17-19. Nje bi nipa ese okunrin kan iku joba
nipa enikan; melomelo li awon ti ngba opolopo ore-ofe, ati ti
ebun ododo, ti nwon yio si joba ninu iye nipa enikan, Jesu
Kristi.
Nje bi nipa ese enikan idajo ba ba gbogbo enia si ebi; gege
beeni nipa ododo enikan, ebun ofe de fun gbogbo enia ni idalare si iye. Nitori gege biotise pe nipa aigbagbo enikan, enia
pipo di elese beeni nipa igbagbo enikan, a o so enia pipo di
olododo.
I Kor. X V ., 21-22. Nitori igbati o ti se pe lati ipa odo
enia ni iku ti wa, nipa odo enia li ajinde ninu oku si ti wa pelu.
Nitori bi gbogbo enia ti ku nipa Adamu, beeni gbogbo enia yio
si di a aye nipa Kristi.
N inu awon ese-fa ti a ii oro^mimo wonyi gbelohiin, a ri pe
oruko nwonyi Ode aiye, Ajo; Ode orun, Abem o;
li a fi toka si awon eni naa ti o duro Iotun ati Iosi bi ori
fun araiye ati ara-orun.
Ipb ode ni ile wa ki ise kekere; fun ati-la ona titun, fun
ati-te ilu titun, fun ati-da ija sile on ati-pari ija, gbogbo wa li a
mo ipa ti ode ko ni ile wa.
Ajo ati Abemo. Ki ise oruko bikose ise ti a pin fun won
ni mo fe ki a kiyesi nihin: *e.n. pe awon mejeji a maa pade se
ikomq ni ipinna aiye on orun leekan Ipdun. Awon babalawo
wipe Ajo ni Olodumarefi seojiiara-re sinu aiye nigba iwa se, O
si fi gbogbo atunse aiye le e lowg; ati pe Abemo duro ni ipo
kannaa li orun bi oju Olprun ati alatunse orun. Nigbati Ajo

*e.n. jasi akomona eyini ni.

ORI I

ati Abemo ba pade ikomo, Ajo ni iso gbcgbo ohun ti prun fi


se aiye lati esi wa; Abemo a si so gbogbo ohun ti aiye fi se
prun: awpn mejeeji a si so idi abajp fun ara-wpn, nwpn a si
jiimp gbe gran aiye on prun si etg. Ero yi je pataki kan ninu
ipile isin ti nmii awpn baba-nla wa pejp Ipdppdun bi agbajp
ilu fun ati-bp awpn eniti o te eya tabi orile do ti nwpn irnaa
pe ni egungunisele.
(d) Ija na se lori ohun kansoso ti t ptun-tosin won ni ojii si.
Ode aiye ati ode prun nde gfin kansoso lati pin ohun
gbogbo ti o bg si i dpgbadpgba; araiye ati ara prun jum p
wote pa edii kansoso ti ara prun kg ati-pin fun araiye ninu
re rara. Kili ohun ti iwpnyi ndii lati fihan bikose (1) irerasile
ti Olprun ti O ni ohun gbogbo si fi mba awa enia pin ohun gbogbo tobee ti gfe ati ofo fi je odi mejeeji asp kansoso. Eyiini
ni pe ohun ti o je gfe fun wa jasi ofo fun Olprun, ohun ti o si je
ofo fun wa jasi gfe fun Olprun. Ero yi je pataki kan ninu
ipile isin ti nmu awpn keferi ile wa ma tpse kili o da ofo ti Ifa
ba wipe on ri si wpn. Bi nwpn ba si ti gbg pe ara-prun li o da
ofo ti mbpwa na, nwpn ki tun beere pe kili awpn fi se araprun o? Sugbpn lesekanna ni nwpn a maa tumba nipa jijewp
gbogbo pna ti o ba han si wpn pe awpn ti nje gfe laijuba
ibiti gfe naa ti wa. Ero kannaa yi ti o li eru fun wpn jpjp li o
wa nisale gbogbo suuru ati ipampra ti nwpn imaa fi gba ofo
ti o ba se wpn pe Olprun li O fe bee.
A si ri pelu niti edii kansoso (2) irira ti Olprun Olodumare
ni si abuku isin ati aabp pkan. O ya fun U lati kg gbogbo
isin ati pkan naa ti d mu u wa ju lati gba wpn li abuku ati aabp.
Ese ekini ti o here ori ekini ninu Ifa jeri si planla yi ninu
Olprun. Ese naa wi bayi pe.
7.

Otctpptg, Orgrpprg; gtptp * Ia ijepa, Otptp Ia

*Oluku!uku grg nwgnyi Otgtggtg Orgrggrp Otgtb Tori-tori je ed<

ORI 1
ije imuumuu; tori-tori Ia ifun Obamaakin n lle IranJ6
ia 6 le baa f ohun tori-tori funni.fcjiogbe.
(e) Araiye ko ro ati-tiimba fun ara-orun bikoje lehin
opolopo igbe.
Opo ippnju ati iloyun, Opo egiin on o^uju, gpo
ile-ni kuro laarin enia ati onje enia si ibugbe awon eranko
igbe ati si jije koriko bi maalu, 6po Wkun-omi, opo
idarii-ede, opg ojo sulfuri ati ina, gpo ida ati iyan, ati
eranko buburu, ati ajakale arun, opo ikii;ko ha e pe nwonyi li o kamba pmo araiye, li o te agidi pkan wpn, ti o si nmu
wpn tiimba fun O lprun!
Ero yi je pataki kan ninu ipile isin ti nmii awpn keferi ile
wa m aa tpse kili o da iku tabi arun, tabi ejo, tabi ofo ti Ifa ba
wipe on ri si wpn. Nitorinaa bi Ifa ri iku si wpn, nwpn a bi i

ti a nio lati tpka si ohunkohun ti o wa ni kikun, pipe, ati ailabuku.


Obaiala li a pe ni Obamakin ninu ?se-ifa yi. Mu ?se-ifa naa wa si egbe
pro mimp tinu Bibeli.
Lef. xxii. 20-21. Sugbpn ohunkohun ti o ni abuku, li pnyin ko
gbpdp muwa: nitoripe ki yio da fun nyin. Ati pnikeni ti o ba ru pbp
alafia si Oluwa lati san pjp, tabi pbp ifp-atinuwa ni maalu tabi agutan,
ki o pe ki o baa le da; ki o mase si abuku kan ninu re. 1 Kron. xxviii. 9.
Ati iwp, Solomoni pmp mi, mp Qlprun baba rp, ki o si fi aiya pipe ati
fife pkan sin i: nitori Oluwa a maa wa gbogbo aiya, o si mp gbogbo ete
ironu, bi iwp ba safpri rp, iwp yio ri i; sugbpn bi iwp ba kp p silp, on yiota
p nu titi lai. Wo xxix. 17-19. Emi mp pplu, Qlprun mi, pe iwp ndan
pkan wo, iwp si ni inudidun si ododo. Bio?e ti emi, ninu ododo pkan
mi li emi ti fi tinutinu se iranlpwp gbogbo nkan wpnyi; ati nisisiyi pplu
ayp ni mo ti ri awpn enia rp ti o wa nihin lati fi tinutinu se iranlpwp fun p
Oluwa Qlprun Abrahamu, Isaaki ati Israeli awpn baba wa, pa eyi mp
lailai sinu ete ironu pkan awpn enia rp, si fi idi pkan wpn mulp si pdp rp:
Si fi pkan pipe fun Solomoni pmp mi lati pa ofin rp, pri rp ati ilana rp mp.
Isa. xLii. 8 Emi li Oluwa: eyi ni orukp mi; ogo mi li emi ki yio fifun
plomiran, bppni emi ki yio fi iyin mi fun ere gbigbd.
Joh. iy. 23-24 $ugbpn wakati naa mbp, o si de tan nisisiyi, nigbati
awpn ti nsin li otitp yio maa sin Baba li pmi ati li otitp: nitoripe iru awpn
pni bpp ni Baba nwa ki o maa sin on. Emi li Olprun: awpn pniti nsin i
ko le se alaisin i li pmi ati li otitp.

ORI I

10

lere pe iku araiyetabj.-ti ara-ruit?-J3i:0 ipl


si wpri/nv/on
a bi i pe ejo ara-orun tabi ti araiye a-bojii perekete? Bi
ibP ba si inu ara-orun ninu 6na ibi wonyi, nwon ki itun beere
pe kili awon fi se ara-orun o? lesekannaa ni nwon imaa
itum ba nipa jijewo gbogbo ona ti o ba ban si won pe awon
ko sin to: nwon a si m ura ati-se gbogbo etutu ati atunse
ti m ba mbe ni ipa won.
(e) Araiye ko le pada ri ojurere Olorun lai-si ebo on
etutu.
(f)

Lati orun ni onilaja ti wa.

Gene, viii., 20-2!. N oa si te pepe. fun Oluwa; o si mu


ninu eranko mimp gbogbo, ati ninu eiye mimp gbogbo, o si ru
ebp-pre sisun lori pepe naa. Oluwa si gbp oorun didun;
Oluwa si wi li pkan re pe Emi ki yio si tun fi ile re nitori enia mo.
II Sdni. kxiv., 25. Dafidi si te pepe kan nibe si Oluwa, o
si ru ebp sisun ati ti ilaja. Oluwa si gbp ebe fun ile naa, arun
naa si da kuro ni Israeli.
Heb. ix. 22. O si fere ise ohun gbogbo nipa ofin li a fi eje
wenump: ati li aita eje sile imukuro ese ko si.
Ninu awpn ese-ifa ti a fi prp mimp wpnyi gbe-lohun, a ri pe
nigbati araiye nfe tum ba tpkantpkan, nwpn fi eyi ban nipa fifi
eran-edu kansoso naa ti nwpn ko ti fe ifisile ri spwp si prun:
ewe, nwpn si fi ohun miran ti a yan li ebp fun wpn spwp si
prim pelu li aijiyan. Eyi naa gaan ni aiya ebp.
Bee gege li a si gbp pe Olodumare tikalare li 6 wa idiibu
ija Ode aiye ati Ode prun; tabi bayi pe nigbati ko si omuiija
tabi plaja laarin Ajo ati Abemp, Abemp tikalare tio ti prunw a
li b si diyeinu nawp ilaja si Ajo awo inu aiye. Gbogbo nwpn
yi ndii ati-fi otitp naa ban araiye pe lati pdp Olprun ni ilaja ati
onilaja ti wa iba araiye.

ORI I

11

Isa. 1 :18, Oluwa wipe, wa nisisiyi ki e si jeki a so asoy6


po: bi ese nyin ba ri bi ododo, nwon o si fun bi snoo; bi nwon
ppn bi alaari, nwon o dabi irun agutan. Isa. xiii. 15, Tani
eleyi ti o ti Edomu wa, ti on ti asp arepon lati Bosra wa? eyiti
o li ogo ninu asp re ti o nyan ninu titobi agbara re? Emi ni
eniti nsprp li ododo, ti o ni ipa lati gbala. Nitori kini asp re fi
pon, ti asp re wpnni fi dabi eniti nte ohun elo ifiinti waini?
Emi tikarami ti te ohun elo ifunti waini; ati ninu awpn enia,
enikan ko pelu mi; nitori emi te wpn ninu ibinu mi, mo si te
wpn mple ninu irunu mi; eje wpn si ta si asp mi, mo si se
gbogbo ewu mi li abaawpn. N itori pjp esan mbe li aiya mi,
pdun awpn eni irapada mi ti. M o si wo, ko si oluranlpwp; enu
si ya mi pe ko si olugbero; nitorina apa ti emitikalami mu
igbala wa spdp mi; ati irunu mi, on li o gbe mi ro. On si
wipe: Lootp enia mi ni nwpn, awpn pmp ti ki iseke; on si di
olugbala wpn.
Eyi naa gaan li awpn keferi ile wa npe ni ORUNM LA .

ORI

12

Eleri-ipln,

Ibikeji

Olodumare.'

Ninu iwe wa isaaju a ti se akiyesi 3d pe av/cn baba-nla


wa gbagbo ps ninu planla Olcrun ti enia ko le mo titobi re yi,
Olodumare ti fi Enikan se ibikeji ara-Re, On a si inaa pe
Oluware si imp ninu oliun gbogbo, On a si maa li ohuu gbogbo
him a, On si fi i se eleri ara-Re ninu ohun gbogbo, tobee
ti ko si oliun ti Olodumare mo ti Oluware na ko mo, ko si si
ohun ti Olodumare ri ti On ko ri. Eni naa ni nwon npe ni
pruunmla, Eleri ipin, Ibikeji Olodumare.
Kje, or.a wo ni Orunmla fi je Eleri ipin?
Awon babalawo fi idahun si ibeere yi iatinu odiiifa wa
gege bi cyiti a ko si isale nihin.
(1) Orunmla je Eleri-ipin nitori On ati Olodumare li o
jumo nse ikomo lode crun.

PL

Olodumare pclu Orunmla lo ill ara-won mo ile0 / 0 '|^ o m o lorun, gbogbo orim nks idaro wipe Tani yio lo
isilekun naa?
;u gbo o siwaju !o ifowo le ii?kim; beeli Qrunmla
Etu
dahun lati inu ile nwipe, Lesi nkan kun Osin kakaka, lesi
nkan kirn Osin lelele? O dahun o ni cmi Etu ni, obeje.
Sugbon Orunmla dahun si i pe ptu obeje, Olodumare ni
ki o dehin o; o til rnp igbanaa ri? tab! o til ba won Ip sikomo
ri? Eeeni Etu obeje pada sehin.

ORI

13

Edii gbo o m on yio ba won silekun; beeli Qrunrnla


beere wipe Lesi nkan kun Osin kakaka, lesX nkan
kiin Osin lelele? O dahun o ni emi Edii ni, ibaaraa
a fija gb oko;
Sugbpn Orunmla dahun si i pe Edu ibaaraa, Olodumare
ni ki o dehin o; o ti i mo igbana ri? tabi o ti i ba won lo
sikomo ri? beeni Edu ibaaraa pada sehin.
Agbpnrin gbp o ni on yio ba wpn silekun; beli Orunmla
dahun wipe Lesi nkan kim Osin kakaka lesi nkan kun
Osin lelele? O dahun o ni emi Agbpnrin odogija onila
afifen.
Sugbpn Orunmla dahun si i pe Agbpnrin odogija,
Olodumare ni ki o dehin o; o ti i nip igbanaa ri? tabi o ti i
ba wpn Ip sikomp ri? beeni Agbpnrin odogija pada sehin.
Ira gbp, o ni on nip ba wpn silekun; beeli Orunmla
beere wipe lesi nkan kun Osin kakaka, lesi nkan kiin Osin
lelele? O dahiin o ni emi Ira oniiwo kansoso ni.
Sugbpn Orunmla dahun si i pe Ira oniiwo kansoso,
Olodumare ni ki o dehin o; o ti i mp igbanaa ri? tabi o
ti i ba wpn Ip si ikomp ri? beeni Ira oniwo kansoso pada sehin.
Ariwo ta lode prim pe tani yio ha ba-ni silekun Osin?
Nigbanaa ni Edun gbp, o jade wa o ni on yio ba wpn de
ibe wo; o Ip ifpwp le ilekun, o si gbp Orunmla mbeere wipe
lesi nkan kun Osin kakaka, lesi nkan kim Osin lelele? O
dahun o ni Emi Edun mil ni 6!
Sugbpn Orunmla dahun si i pe Iwp Edun oloju
fokifoki, Iwp Edun plpwp ppjpppjp, dehin o; mp igbanaa,
tabi o ba wpn yun be ri?
Edun dahun o ni

Oju mi meji fokifoki yi


Mo fi ka ibo f Olpfin je;
Owp mi meji ppjpppjp yi
Mo ii ka ibo f Olpfin je.

ORI 2

14
Orunmla dahun o ni

Haa! O to, Edun olgwo pojp, Edun elese pojo;


Edun oloju foki, maa tun rora:
Itan ti o pa sile ma to 6!

Nigbanaa ni Edun silekun wole ikomo, 6 m ekiin


sekiin igbe, 6 m ohun sohun iyere, o ne.
Ogijan, Edun ma mba won to re;
Ogijan, Edun mba won lo. *

(2). Orunmla je Eleri-ipin nitori on ni Olodumare fi


je d ri fun gbogbo awgn iriinmale ati oba, li aiye ati
li orun.

9 Bi a ba dupe oore ana a gba omiran: a da a f Ori*


'nlo si awujo gbogbo ininmale lo ipobi oore.Ejiogbe.
10. Sese-ooloogoo-sese adifa f Orunmla nlo ba
gbogbo oloja inu aiye jijakaadi.*
O mii AlA ra o da a,
o ko gbogbo eru re ; o d Ajero o ko gbogbo eru r e : o
*Ifa ti a Id nihin ie apa ikehin gsg kan ninu Ejiogbe. o si se gkan
ninu awon esR ti n li erii )u[b fun babaiawoTatTH! Agbara ni m oT ilnu
EabaSwo mi ki i fun mi: sibe . eru ba a tobeg ti o ii mu ini IpsTikoko kan,
ti o SI mu enu sunmo eti mi nki i k^I^elgl
~
~

*Itan yi vvi siwaju pe Olodumare ji, O mu obi oore (e.n. obi olori tabi
alase) sil?: o ni on nfj eniti yio ba on pa a ninu gbogbo awpn Irunmale.
Ogun de o pa a ti, o joko sibe; gbogbo irunmale de Ipkpgkan nwgn pa
obi oore ti, nwgn si joko sibe nleri de gniti yio wa ipa obi ti awgn pa ti.
Nikehin ni nwgn ri ti Ori yg si wgn o nyi bgwa gbirigbiri, o de o mu obi
naa kan, o pa a, ariwo ta: Olodumare ni Qri, jvyg ngg ii o to obi oore
jpa lootg. Beeni gbogbo irunmale bgresi iba Ori jowu ipo gla yi.
Nwgn SI sii-mg g lati ba a ja, sugbgn ko si gniti o da Ori ninu gbogbo irunmale, Ori Io da gbogbo wgn Igkggkan. O da Qlgta sile Ado, o da
Erinmi sode Qwg, o da PgeP?? sode Asin; o da Orisa sltapa, o da
Ogun slle-Ire, o da Obalufgn si lyinde: o da Qrunmla slle-Ife.
*Nigbati Ewi ti gburo isegun Oruunmla, o sa tg awgn awo Ig igbg
ohun ti on le se ki Oruunmla ma le da on; a ni ki o ru owuuru eku,
owuuru eja, pelu igo gti kan. Ewi gbg o o ru gbogbo nkan naa. Bi
Oruunmla ti gbe ija de aafin, Ewi jade si i, o yara ko gbogbo eku ati eja
wgnni ti i li aiya, o si gbe igo gti naa fun u mu. Orunmla je o mu yo
tan, gti gbe e sanle: bgeli Ewi se da Orunmla, ti o si ko gbogbo gru awgn
glgja-lgja li Orunmla ti da. Ayaani a nwipe Ko si gba bi Ewi. Ayaani
Orunmla ni bi a ba da on, ki a si maa ko on!

ORI 2

15

da gbogbo oloja-loja inu a.iye o ko gbogbo eru won tan o


wa mu. ori le ile Ewi ,
Ose meji.
(3), Orunmla je Eleri-ipm nitori on li 6 gbe eru kiki
ori nijo ti awon irunmale ndu eru oro gbe li orun.
11.
Ewpn-bale-ro-worojo adifa f Orunmla a bii fun
gbogbo irunmale, Olodumare deriikale O ranse *pe gbogbo
won ki nwon wa igbe e lo sinu aiye. Okanran-egiitan.
Akiyesi.Awon ese-ifa nwonyi ati itan won ti a ka
nihin fihan dajudaju pe okan awon baba-nla wa nje won
leri pe Enikansoso ni mbe lehin Olorun Olodumare ti 6
le mo ipin ohun gbogbo li ayie ati li orun; ati pe nipa imo yi,
Enikansoso naa ni ise Ori fun ohun gbogbo.

*Ik9 Olodumare de odo gbogbo irunmale, ko si enikan ninu won ti


o ni i loliun; o de pdo Orunmla, Orunmla fun u ni itan adie kan ati opp
onje. Nitori oore yi, ikp naa sofofo fun Orunmla pe ki o mase kanju
gbe eru nitori is? gbogbo mb? ninu karahun li akata Olodumare.
Es? gbogbo irunmal? pe, nwpn ndu eru gbe niwaju Olodumare, eyi ngbe
eru owo, eyi ngbe eru asp; sugbpn ikp Olodumare nfi fere wi tantan fun
Orunmla bayi pe: Oruunmla, ma sedp joko o ! ori mb? ninu aaihun.
Bayi ni Orunmla sedp joko nwo gbogbo irunmale titi nwpn fi ko gbogbo
prp kpja Ip sinu aiye. Orunmla dide nigbati awpn irunmal? Ip tan,
o rin Ip gaara si akata Olodumare, o si mu aaihun (karahun) naa jade ti
ib? wa, o mu pna lie Aiye ppn. Orunmla ba gbogbo irunmale nwpn
tidi si ati-jade si aiye, o bi v/pn eetiri, a ni omi bo gbogbo oju aiye, ko si ile
nibikibi lati ti prun bp si.
Nigbana ni Oruunmla tpwpbp inu karahun re yi, o mu awpn kan ti
inu re jade, o si sp p le oju omi; o tun tpwpbp ib? naa, o bu ikunwp kan
erup? da sori awpn naa; o tpwpbp p nigba keta o mu adi? kan oniigan
marun jade, o si sp p le ori awpn naa p?lu. Adi? yi b?resi erup? die naa
itan, bi o si ti ntan a, beni omi nsa s?hin ti il? si mgbaye.
Oruunmla ti o da il? li o kp bp sori il?; on ko si j? ki awpn irunmal?
wpnni bp sori il? titi nwpn fl ko gbogbo ?ru prp ti nwpn ru ti prun wa le e
Ipwp. lyekiye ti o si to loju Orunmla ni on nfifun wpn pada; gbogbo
irunmal? si tumba fun u patapata. Orunmla si nkprin bayi wipe
Aiye ma nwa
Iwa r iwa o, Iwa Iehin, Iwa!

16

ORI

Awon otitp naa niye lori jpjo ninu ipile isin ti a ba Ipwo
awpn baba-nla wa (ka iwe Mni, ewe 16-17); nitori nwon
nfihan pe awon keferi lie wa ti ni imo wiwa Jesu Kristi. A o
mii awon ohun akiyesi meji naa wa segbe pro Iwe Mimp
Olprun fun ifiwe ki a ba le ri pna ti a le m aa 16 wpn lati ba
awpn keferi ile wa sp aspye nipa ti Kristi.

Enikansoso ni mbe lehin Olprun Olodumare ti o le


mp ipin ohun gbogbo li aiye ati 11 prun.
(a)

(b) .

Enikansoso naa yi ni Ori fun ohun gbogbo.

Job. x x x v i i i . 4-11. Nibo ni iwp wa nigbati mo fi


ipile aiye sple? Wi bi iwp ba moye! Tali o fi iwpn re lele,
bi iwp ba mp, tabi tali o ta okiin wiwpn sori re? Lori ibo ni a
gbe kan ipile re mp, tabi tali o fi okuta igun re le ile? Nigbati
awpn irawp owurp jum p kprin pp ti gbogbo awpn pmp
Olprun nho iho ayp? Tabi tali o fi ilekun se omi okun mp,
nigbati o ya jade bienipe o ti in u tu ja d e w a ?
Nigbati mo
fi awp-sanma se asp re, ati okunkun sisu se pja igbami re?
Ti mo ti pase ipinnu mi fun u, ti mo si se bebe ati ilekun.
Ti mo si wipe: nihinyi ni iwp yio de, ki o ma si rekpja, nihinyi
si ni igberaga riru omi re yio gbe duro mp .

Jobu ko le dahun gbogbo prp-imp wpnyi ti Olprun bi i


leere ninu ori 38 de 41. Mo si le sp pe ko si ninu araiye ti o ti i
fpwpspiya pe on le dahun wpn bikose Enikansoso naa ti
ise Qgbpn Olprun. K a ese wpnyi:

Owe vm. 22-30. Oluwa pese mi ni ipilese iwa re, saju


ise re atijp. A ti yan mi lati aiyeraiye, lati ipilese tabi ki ile
aiye ki o to w6. Nigbati pgbun ko si, a ti bi m i; nigbati ko si
orisun ti o kiin omi pipp. Ki a to fi idi awpn oke nla sple,
saaju awpn oke li a ti bi mi: Nigbati ko ti ida ile aiye, tabi
petele, tabi ori erupe aiye. Nigbati o nse ipile awpn prun.

ORI

17

emi \va nibe: nigbati o fi osuwon ayika le oju ogbun. Nigbati


o so avypsanma Igjo soke: nigbati o fi agbara fun orisun ibii.
Nigbati o fi ase re fun okun, ki omi re ki o mase koja enu re;
ati ofin re fun ipile aiye. Nigbana emi wa lodo re bi onise:
emi si je didun inu re lojoojumo, emi nyo nigbagbogbo niwaju re.
Tani ha li eni naa ti o fgwosoiya bayi bikose Kristi
Eniti a pe ni agbara Olorun ati ogbon Olorun i Kor. i,24.
Eyi naa gaan li awon keferi ile wa mpe ni Orunrnla.
Sugbon Kristi naa ti ise ogbon Olorun ni Ori fun ohun gbogbo.
Efes. i. 22. O si ti fi ohun gbogbo sabe ese re, o si ti
fifun u lati je ori lori ohun gbogbo fun ijo enia O lorun.iv. 15. Ki a le m aa dagba soke ninu re li ohun gbogbo,
eniti ise Ori, ani Kristi.
Ati Kristi naa yi ti ise Ori fun ohun gbogbo li Olorun fi se
Eni apesin aiye ati orun:
1 Kor. xi, 3. Sugbon mo fe ki enyin ki o mo pe,
Kristi li ori olukuluku okonrin; ori obirin si li o k o re ; ati ori
Kristi si li Olorun. Filip, ii. 10-11. Pe li oruko Jesu ni ki
gbogbo eekun ki o m aa kunle, awon eniti mbe li orun, ati awon
eniti mbe hi ile, ati awon eniti mbe nisale ile; ati pe ki gbogbo
ahon ki o maa jewo pe Jesu Kristi ni Oluwa, fun ogo Olorun
Baba. Heb. i. 6. Ati pelu nigbati o mu akpbi ni wa si
aiye, o ni, Ki gbogbo angeli Olorun ki o si m aa foribale
fun u Or. Daf. x c v i i . 7. Oju yio ti gbogbo awon ti nsin ere
fifin eniti nfi ere se ileri ara won: e maa sin i, gbogbo enyin
olorun.
Ona wo ni Orunrnla fi je Ibikeji Olodumare? Awon
babalawo fi idahun si ibeere yi latinu odu-ifa gege bi eyiti a kp
si isale nihin:
(1).

Orunrnla je Ibikeji Olodumare nitori On ati Olodumare li o jum p here iwa nigbati nwpn ko tile ti i
ni ohunkohun miran ju ohun - Iwa - Olorun.

ORI

18

12. Ojii mpon Olodumare, ojii mpon Orunmla:


Olodumare ni ki Orunmla rubo; Orunmla ni ki Olodumare
naa rubo ke.
Nwon jum p yan asobilikl eranla kookan
ati ogbopgbokanla li ebp fun ara-wpn. Awpn mejeeji
gbp ebp nwpn rubp.Ejiogbe.**
(2).

Orunmla je Ibikeji Olodumare nitori lehin Olodumare, On nikansoso li o kii ti o tiin kapa Esu.

13. Eni buruku nsalp kuro loju Olodumare, Olodumare


ke-le e wipe E mii u ! Eni buruku tese mp rin nip,
beeli a ko ri enit o le mu u sile ninu gbogbo ininmale t o
pejp siwa prun.

Eni buruku la won kpja patapata tan 6 wa kan Orunmla,


Orunmla m u u sikun o fa a pada Ip fun Olodumare, O lodu mare gbe e seewpn.

Ayaani oo ri i Olodumare wipe ki Orunmla joko ti On:


O ni Iwp Orunmla nikansoso ni ki o maa ri mi fin ninu
gbogbo ininmale. Ejiogbe.
Akiyesi.Awpn ese-ifa nwpnyi ati itan won ti a ka
nihin fihan pe wiwa-siwaju-ohun-gbogbo je ero pataki kan
ti nwpn ni si Olprun: ati pe wiwa ohunkohun miran lehin

*F,yi tii ppa


ti a kini
ese ti o li eru julp fun babalawo lati ki.

'*11

iwe yi:

Itan abami yi wi siwaju pe nigbati Olodumare ati Orunmla rubo


yi tan, bi nwpn ti jump nrin Ip, nwpn jin sinu pfln nla kan; nwpn si wa
ninu ppplppp ebi nibe fun pjp pipp tobpe ti nwpn ko fi le jade mp. Ni
alabapade ni Edun wa iba wpn ninu ippnju nla yi, o ni Haa! o yara nip
iwa eso igi gbogbo ka wa ifun wpn je nibe titi oju wpn fi wale, ti imi fi ko
wpn die lati goke.
Nigbati nwpn goke tan, sibpsibe nitoriti ara wpn
koi tii padabp sipo tan, nwpn Ip iti ara-wpn mp odi ti a mpe ni Odi Ikomp
li ode prun.
lyoku itan yi li a ti sp saaju ninu pse kejp ti iwe yi.
Asiri nla yi ti Edun nikan mp li o fi ni igboiya lati silpkun wple ikomp
Orunmla ati Olodumare Iptp (wo pse kejp).

ORI

19

OloruQ na Olgrun li ebo kan; ati pe nl riru ebo ula yi, ogboogba ni inawo re fun (31odumare ati Orunm la: ati pe ko si
enikan ti o kapa Esu bikose Eniti o ba Olorun dogba.
Awon otito nwonyi niye lori jojo ninu ipile isin ti a ba
Ipwo awon baba-nla w a: e.n. pe nwon ya Olorun Olodumare
tikalare ati ohun-iwa Re kuro lara ohunkohun ti ise ohun-eloipile-eda, nwon si ya Orunmla ati ohun -iwa re bakanna kuro
lara ohunkohun ti ise ohun-elo-ipile-eda.
Bi a ba mu awon ohun akiyesi wpnyi wa si egbe prp Iwe
Mimp Olprun fun ifiwe, a oo ri pna ti a le m aa 16 wpn lati ba
awpn keferi ile wa sp aspye nipa ti Kristi.
(a). Wiwa Olprun siwaju ohun gbogbo je ero pataki kan
ti o ye ki a ni si Eniti a pe ni Olodumare.
Or. Daf. 90. 2. Ki a to bi awpn oke nla, ati ki iwp
ki o to da ile on aiye, ani lati aiyeraiye, iwp li Olprun.
Job. x x x \ i . 26. Kiyesi i, Olprun tobi, awa ko si mp
bi o ti tobi to! beeni a ko le iwadi iye pdun re ri.
Rom. x i. 36.
ohun gbogbo.

Nitori lati pdp re, nipa re, ati fun u li

Heb. Hi. 4. Lati pwp enia kan li a sa ti kp olukuluku


ile; sugbpn eniti o kp ohun gbogbo ni Olprun.
Ifi. /. 8. Emi ni Alfa ati Omega, ipilese ati opin, eniti o
mbe, ti o ti wa, ti o si mbpwa, Olodumare. iv . 11 Oluwa,
iwp li o ye lati gba ogo ati pla ati agbara: nitoripe iwp li o
da ohun gbogbo, ati nitori wiwu re ni nwpn fi wa ti a si se
da won.
Ero wiwa Olprun siwaju ohun gbogbo U o mu awpn
baba-nla wa kan akoko kan ti oju mppn Olodumare ti o si
m ppn Ibikeji Re pelu; e.n. pe akoko kan ti Olodumare ati
Ibikeji Re ti wa li aitii da edakeda kan, ani nigbati a koi tii
da nkan naa tikalare ti ise ohun-elo-ipile-eda.

20

ORI

Niti OIoTun, gbogbo eda li o ti ban fun Olorun lati


gbogbo aiyeraiye bienipe a ti da won; sugbon niti awa enia,
a ko le ri tabi ki a ni ohun ti koi tii si.
Ohun ijinle nlanla si
ni ero yi li okan awon babalawo ti o ba gbo fa de ibe ni ile
wa; nitori nigbati a tiin fi ibeere yi fun won pe Tali eniti o
kg wa pato ninu Olodumare ati Orunmla? nwon dahun pe
Ko si eniti o mo eniti o kp wa ninu won nitori Li ojp ti a
ti mu oko li a ti mii agbe. *
Eniti o ba ro idahun kekere yi wo yio ri ijinle ero ti
awpn baba-nla wa fifun ohun-iwa Olodumare ati Ibikeji Re.
(b). Wiwa ohun-kohun miran lehin Olorun na Olodumare li ebp kan.
(d). Ni riru ebp nla yi, pgbppgba ni inawo re fun
Olodumare ati Ibikeji Re.
Isin otitp, e.n. oju ibp ati pna m gba-bp ti o se itewpgba
Ipdp Olprun Olodumare je ilana a -tpwp Ontikalare wa:
ati bi ko ti si isin kan ti o pe-ye lain! ebp ati irubp, o daju
pe araiye ko le tikarawpn ronu kan ebp ati irubp laisi ifihan
a tpwp Olprun wa. Nigbati a ba si ro o pe bikose Olprun
Olodumare ba tewpgba ebp ti mbe ninu isin kan, isin naa
ko le igbe oliisin, yio wa idaniloju pc ebp ni kdko ati emi isin.
Ki ha li ebp? Ebp ni nina ara-eni tabi ohun ti o dipo
ara-em fun ati-mu anfaani ba ara-eni tabi elomiran; eyi ni
owurp ebp.
Ero yi gaan ni awpn keferi ile wa nl sipa ebp nigbati nwpn
nwipe Olodumare rubp tabi Orunmla rubp e.n. pe nwpn na
ara wpn jade ki nwpn ba le ni ohun gbogbo wpnyi ti a ri
ati ti a ko ri. Pataki kan li o si je ninu igbagbp wpn pe ohun

*Ki akawe yi ro o jinle: Ewo li o ko wa? ile oko ti a san, tabi


eba oko naa? Iwo yio si ri pe l?sekannaa ti a ti beresi sisan oko, leseicannaa ni agbe re iti ihan p?lu r6.

ORl

21

gbogbo ti a ri ati ti a ko ri (e.n. gbogbo eda), ni ati ibere ati


aarin ati opin wiwa won latinii ati nipase ebo ti Olodumare
ati Orunmla rii li owuro iwa.
Nje eyi mu ki a ri ip5 nlanla
ti nwon fifun Orunmla niti pe ki o je enikansoso naa ti t on
t Olodumare jumo rubo gbogbo eda.
(e) Ko si enikan ti o kapa Esu bikose Eniti p ba Olodumare dpgba ninu ohun gbogbo.
Lotitp ni awon enia ile wa npe Esu ni Elegbara, sibe nwon
njewo ninu isin won pe Olodumare ati Ibikeji Re lagbara ju Esu
lo fiiri. Nigbati a si bi won leere pe Eetise ti e fi mbo Esu to
bayi nigbati e mp p li eni buruku? idaliun ti awon babalawo fifun ibeere yi ni wonyi pe,
Olprun li o da Esu, ti O si fi i je oye alagbara spdp araRe Iphun. Nigbati Olprun si mp pe Esu ko tiin san mp. On
kannaa li o le e wa sinu aiye. Agbara Olprun tobi ju ti Eu Ip
fiiri, sugbpn bee gege ni agbara Esu si tobi jii ti awa pmp
araiye Ip. Ida ti Olprun ti da Esu lati phiin wa ni ko se ipa-da
Ipwp awa pmp araiye li o je ki a kiiku maa be e ki o ma baa fi
buburu re se wa. Enyin ko gbp bi owe wa kan ti wi pe Bi ko
rpp-nii 1 apa baba, a rpp-nii Iapa iya? Qrun Ipphun ko
san Esu, sisan li aiye wa isan jii prun Ip ni.

Ero yi m'ye lori jpjp niwpnbi o ti tpka si pna pataki ti a ba


m aa lo iyanju wa si laarin awpn keferi ile wa lati mu wpn mp
daju pe Olprun ko le Esu bp si aiye lati maa pa araiye li aiya
niican, sugbpn O si ti ran Enikan ti o le kapa E?u wa sinu aiye
pelu lati je Ogagun igbala araiye: ani Eni naa Jesu Kristi
Olugbala.
Luk. xi 21-22. Nigbati pkpnrin alagbara ti o ham pra ba
nsp aafin re, erii re a wa li alaafia: Sugbpn nigbati pkpnrin
alagbara jii u ba kplu u, ti o si segun re, o gba gbogbo iham pra
re ti o gbekele Ipwp re, a si pin ikogun re.

22

ORI

i Tessa, v. 8-10. ugbon e jeki awa ti ise ti osan, ki a ma


wa li airekoja, ki a m aa gbe awo-aiya igbagbo ati ti ife wo; ati
fun asibori irin, ireti igbala. Nitoripe Olorun ko yan wa fun
ibinu, bikose lati ni igbala nipa Jesu Kristi Oluwa wa. Eniti
o ku fun wa, pe bi awa ji tabi bi awa siin, ki a le jum o wa laaye
pelu re.
Heb. II. 14-15. Nje niwon bi awon omo ti se alabapin
ara on eje, on tikarare pelu si mu ipa ninu re naa; pe nipa iku
ki o le pa eniti o ni agbara iku run, eyini ni Esu; O si yo
awon, nipa iberu iku, ti mbe labe ide li ojo aiye won gbogbo.
i John. ii. 8. Enikeni ti o ba dese ti Esu ni; nitoriti Esu
ti se lati igba atetekose. Nitori idi eyi li Qmo Olorun farahan
ki o le pa ise ti Esu run.

OBI 3

23

ORi i n

Oluwa m i A m o im o ta n !
A ko mo O tan ko se,
A ba mo O tan iba se ke.

Ede yi Oluwa mi ninu isin je eyiti awon keferi a m aa 16


ni ibola fun orisa won. Ninu isoro lasan, a mo bi lilo ede naa
yi ti woopo to ni ile wa. Aya a maa lo o ni ibola fun oko re,
erii a m aa 16 o ni ibola fun olowo re, awon enia ilu a m aa lo o
ni ibola fun oba won: sugbon gbogbo enia ninu isin ni
imaa 16 o ni ibola fun orisa won. Sugbon ilo re nihin li enu
babalawo ninu adura ati isin re miran si Orunmla ati O lodumare je ibola ati ibowo fun awon mejeeji na ni iru 6suwon ti o
rekpja eyikeyi ti aya 16 fun oko re, tabi eru fun olowo re, tabi
oloto ilu fun oba re. Osuwon naa tile rekoja eyiti awon
elomiran fi imaa bu ola ati owo fun awon orisa ti nwon mbo
lehin Orunmla.
Enikeni ti o ba si fpkanbale ro ipo ti awon
babalawo to Orunmla si li egbe Olodumare yio mo iru ifokansin ti nwon fi imaa pe e li Oluwa. O mii-ni ranti pro
wpnyi ti mbe ninu I Kor. viii. 5-6 Nitoripe bi nwpn tile
wa ti a mpe li Olprun, iba se li prun tabi li aiye, (gege bi ppp
plprun ti wa, ati ppp oluwa), sugbpn fun wa Olprun kan li o
wa. Baba, Ipwp eniti ohun gbogbo ti wa, ati ti eniti gbogbo wa
ise; ati Oluwa kansoso Jesu Kristi, nipase eniti ohun gbogbo
ti wa, ati awa nipase re.

Anda mungkin juga menyukai