(1)
(2)
(3)
(4)
(5)
(6)
(7)
(8)
(9)
(10)
(11)
(12)
(13)
(14)
(15)
(16)
(17)
(18)
A bu Iyerosun so;ju; opo;n Ifa;, Odu ti; a te si; aarin o;po;n Ifa; ni; odu ti; a da; ele;yii; ti;i; se
Ogbeyo;nu;. Ni; apa; otu;n re ni a ma;a te ekeji odu na;a si; ele;yii; ti;i; se Ogu;nda;bede;. Ni; apa;
osii re nia ma;a te Osetura; si;.Ti; opo;n ba; te;ju; paa;paa;, ni; alafolaji ni a ni; la;ti te Ejiogbe si;.
Opon Ifa; na;a gbo;do wa lo;ri;i apo abira ti; a te; si;le;.Ni; apa; otu;n apo abira ni a ti ri; Irukee re
Ifa;,ni;gba ti; Iro;ke;-Ifa; wa ni; apa; osi ti;i; se apa; ala;a;fi;a. Ni; iwa;ju; o;po;n Ifa; yii; ni igba; ebo o;
wa. Omi ati epo je dandan ko; wa; ni; tosi; eni to; n;setutu Ifa; ni;tori; eyi;ke;yii; ti; Ifa; ba; mu;n. o;
see;se ko; je; me;je;e;ji.
Iba oo!
Iba atiwa;ye; ojo;!
Iba atiwo oorun!
Ibaa baba;!
Ibaa yeye!
Iba olu;wo!
Iba ojugbona!
Iba ki;ridi awo Idita!
agbo;ruku awo Ale Ife!
(2)
BO:lu; ba; lo !Olu; ni;i; sin i;n! Osetu;ra; wa;a; ba; ni la;se si; Ebo yii;,"
Atepo
Arepo
Awon me;jeeji ni wo;n jojo faa;kara nuwo;
A di;fa; fe;jerindi;nlo;gu;n oro;du
Ni;jo; ti; wo;n n; gbe;bo lo so;de orun
A di;fa; fu;n Osetu;ra;
Eyi; ti; ;n ba won gbe;bo lo so;de orun,
O: gbo; ri;ru; ebo o; ru;!
O: gbo; Eeru o; si tu eeru
Nje; taa lo; tete gbe;bo de; bode
Osetu;ra;
Osetu;ra; lo; tete gbe;bo de; bode
Iwo Akinoso;
Ose; oni;nare!
Ose; awu;rela je; ke;bo o; fi;n.
Iwu;re
"Ifa; je; ke;bo yii; o; fi;n je; ke;eru o; da"
(4)
Ogu;nda;bede; wa;a; su;re; ko;o wa;a; gbe;bo enikeji re lo sa;lade orun kokoooko ko; se si;
tolo;ore:
Gii;ke
Awon lo; di;fa; fu;n Ori;obo
Wo;n ni; to; ba; ti ji ni; ko; ma;a sebo ara li;le
Origidi pi
A di;fa; fu;n Iro
Ni;jo; ti; n; ra;run kange;
Ebo n wo;n ni; ko; wa;a; se
O: gbe;bo o; sebo
O: gbe;e;ru o; tu eeru
Iro lo;un sebo akasu eko
Bi; Iro ba; ja; lo;ri; igi
A farun fa;la;run
Arun ti; n; se wa; esi;n ta;n o
Ipepe;re; aaka laa; mu se agbon la;a; fi gbon arun ohu;n danu
Iwu;re
Ifa; da;kun da;bo je; ki; araa eni to; da;fa; yii; o; ma;a le nig;ba gbogbo.Arun araa re ko; su u; mo;
imi; ko; to o; mo; ito.
(5) Ejiogbe da;kun da;bo fiye de;nu; ko;o fiye de;kun!
A kii; gbo;ju; ka; folo;ja je;ri ejo;
Ifa; la;a mo; o fOlo;ja je;ri ejo;
Sugbo;n iro; laa gbodo pa mo; on
Agunmonna awo eba; ona
Oun lo; di;fa; fu;n Sebo;osoosa
Eyi; ti;i; sele;gbaa; eni,
Awa; sebo
Awa; soosa,
Ifa; wa;a; ri; are;gbaa; eni.
Iwu;re
Oru;nmila wa;a; so la;monri;n di olo;polopo eni lo;de isa;laye;, ki; wo;n o; ma;a ran-a;n lo;wo;.
(6) Okanran me;ji, Ebo yii; ti di eboo re ko;o ba;ni se e; dandan ko;o se;gun awon ota;a re,"
(8) Obarabogbe! ebo yii; di tire, ko;o je; ke;bo o; fi;n ki; eru o; da ko; do;de orun ko; se si;
tolo;ore,
Itan Ega o see; salejo
A di;fa; fu;n Ajankoorodugbe
Eyi; ti; n; sawo rele; Ele;wii;
Awa; ru;bo
Ebo; da na; o
A Momo sebo Ajankoorodugbe
Ifa; wa se
Iwure
Ifa; je; ki; ebo yii; fi;n ko;o je; ko; da ko; do;de orun ko; se si; tolo;ore.
(9) "Iworiwofu;n agba;agijan omooburu Ifa;"je; ke;bo yii; o; fi;n ke;tutu yii; o; gba:
Iwori towo;fu;n! towo;fu;n
Iwori tesefu;n tesefu;n
(11) Irete me;ji ko;o wa; ko;o ba; ni la;se se;bo na;a
Iwo o te
Emi o te
Ote; di me;ji
O: dododo,
Awon lo; di;fa; fu;n Alo;ri;ire ma; lese ire
Ibi Or; n; gbe mii; re,
Ese mo; mo si ibe
Da;kun da;bo
Iwure
Ibi reere ni ko;o gbe; e de;, ese e re, da;bo ma; si ibi rere, ma;ma sina.
Pa Igu;nnugu;n bofa;
Awo won n;le; Ala;ra;
Pa Awodi bo Ose
Awo oke Ijero
Pa Ati;oro Bogu;n
Awo ara;ka ni; mode
Agbo;nmi ni;i; wo;le; eja
Apajuba ni;i; bile; aparo wo;
Olugbo;n;gbo; tiila
Ni wo;n fi; n; se;gun ogu;lutu
A di;a; fu;n la;yigbo ogege;
Ti wo;n mole; iku; e ta;n la;ye;
Wo;n n; pilee torun
If lo; domimi mi ogege
Ela ba; ni wo;le; orun
Barapetu ba; wa tu;n taye; mo
A bu; won lo;run awa o wa; mo;
Iwariwari orun
Ota; a bori; poogodo
Ile; iku; mo n; wo; lo;run
Ogerere ile; iku; mo n; wo; lo;run
Ko ni; bu; o la;yigbo
Arundu o ko; ni;i ;bu; o la;yigbo
Arundu
(12) Ogundasa: Ebo yii mama di ti re, koo ba ni se dandan, Saa reere ti
je ko wa si imuse,
Ogu;nda; saa; saa;
A di;a; fu;n Ala;a;sa
A bu fu;n Oni;ka;hu;n
Ni;jo;o wo;n n; ba;raa wo;n sore; atilewa; la;i;la;i;
Wo;n a ni; ka;nhu;n mo ti daba;ku; aa;sa ojo; tipe;
OR
Abayi;n igbo ni;i; mo;ri; pijegi;
Babalwo Oge lo; sefa; fu;n Oge
Oge n; tikole; orun bo wa;ye;
Nje; omode; kii; mo;taa; poge;
Eyin oge; lota; ti ya;a ba;le
Ibi; se mi
Ibi; se mi loge; n; ke;
lamonrin nda,
Ifa; da;kun da;bo fiye de;nu; ko;o fiye de;kun, olo;ore re, I fa; ma; je ko; jinna si; i.
(13) Otuakaa:
O: tu; ra;ka
O: rin ra;ka
Erigi lawo agbasa
A di;fa; fu;n won ni; Sesi;-Age;re;
Ni;bi wo;n ti ji; ti; wo;n t;i n; wa; ohun ebo kiri
Wo;n tu;n ko; ohun ebo si;le ta;n
Wo;n tu;n n; wa; ala;woo; kiri
Owo; ti; n; be ni;le yi;
Ohun ebo ni;i; se
Erigi lawo agbasa, Ifa;, a ro;hun ebo
Agbado ti; n; be ni;le yi; ohun ebo ni;i; se
Erigi lawo agbasa, Ifa; a ro;hun ebo
Iwure
Ifa;, gbogbo ohun ebo ti; o; to;ju; kale yi;i je; ko; do;run, a fowo; omode; ru; u, ki; wo;n o; fowo;
agbalagba gba a;......(Babala;wo to; n; ru;bo gbodo fowo; kan ohun ebo pa;ta;pa;ta;...,)
(14)
Irosunopinmi; (Irosunrete):
Ifa; da;kun Oru;nmila da;bo, Ifa; je; ke;bo yii; o; da;lade orun ,ko;o je; ko; fi;n ko; da...ko; da;lade
orun:
Ee;ka;nna; wii;n wii;n win
Awo emi; lo; di;fa; fu;n Emi;
Emi; ti;i; solo;ja ni;nu; ara,
Ebo ni wo;n ni; ko; wa;a; se,
O: gbe;bo n;be
O: sebo
O: gbo; eeru o; tu eeru
Ko;hun ko;hun mo; se emi; olo;ja ara
Ohun o gbodo semi; olo;ja ara.
Iwure
Ifa; ma; je ki; emi re o; bo; ni; ke;kere;....
(15)
Ogu;nda;bede;:Iwo loo; da; ebo ni; Iga;ra; ti; o kii; je; ki; ebo o; fi;n, Iwo loo; da; etutu ni; Iga;ra; ti; kii;
fi;i; gba ,wo;n ni; iru; ebo wo ni? o ni; ebo ti; won o ba; ti pe o; si; ni, a pe o; si; ebo Ogbeyo;nu; ni,
ko;o da;bo ki; o ba; ni gbe; ebo yii; lo si; ode orun, ko; fi;n ko; da, a fowo omo ke;kere ru;u, ki; o
wa;a; fowo; agbalagba gba a;....
Eniyan ti; ko lo;wo; lo;wo;
Wo;n a deniyan la;sa;n
A di;fa; fu;n Ala;ke; Ile; egba;
Ni;gba ti; n; be la;arin ipo;nju;
Ebo ni wo;n ni; ko; wa;a; se
O: gbe;bo
O: ru;bo,
O: gbo; eeru
O: tu eeru,
Oru;nmila ogbo;lu; mesiare eyin o ri; Ifa; awo; ki ti; n; se lo;oro; gangan.
OR
Bede;
Awoo won lo;de Ipo
Awe
Awo ode Ijesa
Ominrinmi;nri;n ara; ira;mori;
Igi ganganran mo;se gu;n mi lo;ju;
Olorun debiti oran kale
A kii; ra;la;wo si; rejereje
Awon lo; di;a; fu;n Olo;fin
Ni;jo; ti; wo;n ke;bo ke;edi ti i;
Olo;fin ni; ki; wo;n o; ma;se ke;bo ke;edi ti oun
Oro;gbo; kan
Oduso kan
Bo;mode; ba; ko;kin ga;ga;a;ga;
A foduso si;le
Esu;n o; pele;suu;n
Ere; o; pele;ree;
Ogundu oga;n
Ni; o; jin lo;ri; araa re
Araa won ni wo;n o mo;o jin
Araa won ni wo;n o; mo;o ku; gbonrangandan
Gbogbo awon ti; n; ba; la;gba;ja; sota;
Gbogboo won ni; ki; wo;n o; mo;o ku; gbonrangandan
Okan yeeyee
A di;fa; fu;n Olu;gun awerooro
Omo ale;ku; gori; odi lo
Ebo ogbo; ni wo;n ni; ko; wa;a; se
O: gbe;bo n; be
O: ru;bo
O: gbo; eeru
O: tu eeru,
Ifa; ba; wa le;ku; lo ni;gba yi; awa o ku; mo;
A momo sebo okanran yeeye
Ifa; ti ba; wa le;bi lo.
Iwure
IFA le;ku; lo fu;n-un, le; Arun lo fu;n-un......
(17)
Oseroyin (Ose;wori): Ifa; da;kun da;bo fiye de;nu; fiye de;kun ba;ni royin ebo yii;
la;lade orun"
(17)
Osetura pele oo! Awurela Akinoso! bo;o ba saaju ebo o si kanhin ebo>
Sugbon ojo ire aje, Ire aya, pipe laye , ........ ba n bo, Ifa sii sile...(aa si owoo re sile , aa fi
owo laa yo fi owoo re raa ri aa ni Ifa je ki o forilagba ayee re ja....)
Leyin ti a gbe ebo lo si ibi ti won o ti gbaa ton.A maa beere lowo Ifa bi a ti maa se
iyerosun oju opon.Boya ki o fomi loo ni, tabi ki a fee si lara.
ABORU ABOYE
SS