ÀDÚRÀ TI EGÚNGÚN
Ilè mo pè o
Ó Egúngún!
Ilè mo pè o
Ó Egúngún!
Egúngún a yè, kíì sé bo òrun
Gbogbo mònríwo
Ó Egúngún!
A kíì dé wa ó, a kíì é Egúngún
Nós vos saudamos quando chegais até nós, vos saudamos Egúngún
Won gbogbo ará asíwájú awo
Ó Egúngún!
Mo pè gbogbo ènyin
Ó Egúngún!
Ki o ma ta etí wéré
Responde rapidamente
Bàbá awa omo re ni a npè o
Ó Egúngún!
Ki o sare wá jé wa o
Ó Egúngún!
Má jè a ríkú èwe
Proteja-nos da ira de È s ú
Má jè a ríjà Ògún
Ó Egúngún
ÀSÉ
oriki òsùn
ÒSÙN
Òsun mo pè ó o
Mo pè o si níní àlàáfíà
Mo pè o sí oro
Mo pè o si níní Omo
Ó l’éwà
A fidé ré Omo
Aquela que enfeita os filhos com bronze
Òsun òyéyéni mò
Ó bá Sònpònná jé Pétékí.
Que como Pétékí com Sònpònná
O bá alágbára ranyanga dìde.
Que enfrenta pessoas poderosas e com sabedoria as acalma.
Oliri pa koko eni pon
Poderosa, não empurre o povo de Iponda.
O ri onise Oba ayi kase
Ela recebe o mensageiro do rei sem respeitá-lo
O je dandan oloran
Ela aceita as palavras do queixoso
O fi aja wà Inu eke wò
Com sua sineta ela fura o ventre mentiroso.
Omo Olu Igbo soki redà omo ni
Não se pode carregar debaixo do braço o filho da mata de Iponda.
oriki òsòósì
ÓSÒÓSÌ